Oduduwa National Anthem

ISE WA FUN'LE WA

FUN ILE IBI WA
KA GBEGA (3x)
F'AYE RII
IGBAGBO WA NIPE
B'ATI BERU
LA B'OMO
KA S'ISE (3x)
KA J'OLA
ISOKAN
AT'OMINIRA
NI K'EJE
K'AMA LEPA
ITESIWAJU
F'OPO IRE
AT'OUN TO DARA
OMO OODUA DIDE
BOSI IPO ETO RE
IWO NI IMOLE
OGO ADULAWO

Comments

Popular posts from this blog

Iya ni Wura

Owe ni Yoruba

Why a union?