Osa Eleye!


Ogbón kan mbe níkùn Asá,
Ìmòràn kan mbe níkùn Àwòdì,
Òkàn níkùn e, Òkàn níkùn mi,
Òkàn níkùn ara wa,
Diafun Òrúnmìlà,
Baba ñ loree b'awon Àjé mulè nígbó Olúkórómójó,
Wón ní kílódé,
O ní nitori kí Ayé le gun
O ní nitori kí igba le rò
Igún lo pé Kaye wa O gún
Àkàlà lo pé k'aya wa O bale
Agbe a gbéré wa
There's a Power in the belly of hawk
Another one in the belly of Eagle
One in your belly, One in my belly,
One all of us,
Instruction of Ifa to Òrúnmìlà,
Who was going to exhibit a divine Vow with Àjé' in the sacred groove of Olúkórómójó,
He was asked why,
He said for him to prosper,
For calmness to descend for him,
Igun had declared that ours shall prosper
Àkàlà had declared our world shall be calm
Agbe shall direct blessings towards us,
Ase,
             ~Oleye_nifa~


Comments

Popular posts from this blog

“The Àjé

Yoruba

Yoruba Value System